Ọ̀NÀLÓJÌN
Ká ṣe ẹrú réderède
Ká fọmọ yá ìwọ̀fà
Ìbí kòju ìbí láyé
Bí a ṣe bí ẹrú
Bẹ́ẹ̀ náà labí ọmọ
Ká fọmọ yá ìwọ̀fà
Ìbí kòju ìbí láyé
Bí a ṣe bí ẹrú
Bẹ́ẹ̀ náà labí ọmọ
Ọ̀dájú lẹni ta ẹrú
Ẹni ra ẹrú kò ṣe ire
Ìyà ẹrú mà pọ̀jù
Taani yóò gba ẹrú kalẹ̀?
Lọ́wọ́ adánilóró
Ẹni ra ẹrú kò ṣe ire
Ìyà ẹrú mà pọ̀jù
Taani yóò gba ẹrú kalẹ̀?
Lọ́wọ́ adánilóró
Ẹni tó mọ̀ ọ́n pa
Ẹni tó mọ̀ ọ́n bò
Ọlọ́run ní gbọkọ́ lọ́wọ́ wọ́n
Olówó ayé tó ń fowó ra ẹrú
Háà! Ìwọ náà si bímọ
Ẹni tó mọ̀ ọ́n bò
Ọlọ́run ní gbọkọ́ lọ́wọ́ wọ́n
Olówó ayé tó ń fowó ra ẹrú
Háà! Ìwọ náà si bímọ
Ewo bíyà ṣe ń jẹ ẹrú báyìí
A gbowó ipá
Háà! Tẹ́ ẹ̀ sì ní ju sáyé yìí
Ẹ wo ẹrú ṣe láàánú
Ẹ o mọ ibi orí ń gbé ọmọ tiyín náà rè
A gbowó ipá
Háà! Tẹ́ ẹ̀ sì ní ju sáyé yìí
Ẹ wo ẹrú ṣe láàánú
Ẹ o mọ ibi orí ń gbé ọmọ tiyín náà rè
Ènìyàn lẹ so mọ́lẹ̀ bí ẹran yìí
Èdùmàrè bojú wayé ẹrú
Gbàwọ́n lọ́wọ́ atúnnidá
Hùn! Ìgbà kan kò lo ayé gbó
Ẹ rántí pé kò sẹni tó gbọ́n ju kádàrá lọ
Èdùmàrè bojú wayé ẹrú
Gbàwọ́n lọ́wọ́ atúnnidá
Hùn! Ìgbà kan kò lo ayé gbó
Ẹ rántí pé kò sẹni tó gbọ́n ju kádàrá lọ
Bówó lo bá ni
O di dandan kó dópin
Bíyà nìwọ sì ń mu bí i gaàrí
Bó pẹ́, bó yá
Yóò dópin lọ́jọ́ kan
O di dandan kó dópin
Bíyà nìwọ sì ń mu bí i gaàrí
Bó pẹ́, bó yá
Yóò dópin lọ́jọ́ kan
Sáká ló dájú
Kòsí ohun tí kìí lópin
Àpọ̀jù sùúrù kòsí
Àyàfi tí kòbá tó
Kọ́mọ tó dẹrú, ọmọ̀ ni
Kòsí ohun tí kìí lópin
Àpọ̀jù sùúrù kòsí
Àyàfi tí kòbá tó
Kọ́mọ tó dẹrú, ọmọ̀ ni
Ẹ rántí ẹ̀san
Ẹ má lo ènìyàn nílò ẹrú mọ́
Ẹ rántí pé
Ọ̀NÀLÓJÌN
ẸRÚ NÍ BABA
Ẹ má lo ènìyàn nílò ẹrú mọ́
Ẹ rántí pé
Ọ̀NÀLÓJÌN
ẸRÚ NÍ BABA
SAY NO TO MENTAL SLAVERY
© Ọ̀títọ́nifá
Main main
Complain! I know you
The slave is suffering
The great suffering of a slave is suffering.
's rẹrú
Let's be slave básubàsu
's réderède
's,'s
Birth of kòju on earth
As a slave
So also labí the son
Heartless heartless
He who buys a slave does not do good.
Your suffering is too much
Who will deliver a slave?
By Reckoning
The one who knows him kill him
The one who knows him
God is everything in them
The owner of the world that buys a slave
Oh! You too didn't give birth
Look at how he is being slaves now
Don't force
Oh! And you have more than this world
Look at the slave slave
You know where your child is taking your child as well.
People are so lit like this meat
May the almighty watch the slave
Deliver them from atúnnidá
Complain! One time does not spend time.
Remember that there is no more wiser than destiny.
What is it?
It must come to an end
You are the one who drinks like that.
As long as it will be
She will end one day
Server is sure
Nothing has no end
Too much patience.
Unless it's not enough
It's a slave that is a slave, he is a slave.
Remember the vengeance
Don't need a slave anymore
Remember that
Main main
Slave is father
SAY NO TO MENTAL SLAVERY
Complain! I know you
The slave is suffering
The great suffering of a slave is suffering.
's rẹrú
Let's be slave básubàsu
's réderède
's,'s
Birth of kòju on earth
As a slave
So also labí the son
Heartless heartless
He who buys a slave does not do good.
Your suffering is too much
Who will deliver a slave?
By Reckoning
The one who knows him kill him
The one who knows him
God is everything in them
The owner of the world that buys a slave
Oh! You too didn't give birth
Look at how he is being slaves now
Don't force
Oh! And you have more than this world
Look at the slave slave
You know where your child is taking your child as well.
People are so lit like this meat
May the almighty watch the slave
Deliver them from atúnnidá
Complain! One time does not spend time.
Remember that there is no more wiser than destiny.
What is it?
It must come to an end
You are the one who drinks like that.
As long as it will be
She will end one day
Server is sure
Nothing has no end
Too much patience.
Unless it's not enough
It's a slave that is a slave, he is a slave.
Remember the vengeance
Don't need a slave anymore
Remember that
Main main
Slave is father
SAY NO TO MENTAL SLAVERY

No comments:
Post a Comment